Reminisce Owo Lyrics
Ẹni fẹ nawo, na mi lowo kia
Ajilete mo ti n wa, lọna Ipokia
Owo n bẹ lapo mi o
Owo n bẹ lapo mi o
Ẹni a ba laba ni baba
Ẹni ba ṣe jura ẹ lọ a jẹgba
I don’t care what they say about me
Ki ma fagbo lọ ni temi Akanbi
Owo n bẹ lapo mi o
Owo n bẹ lapo mi o
Owo n bẹ lapo mi o
Owo n bẹ lapo mi o
Ki ma fagbo lọ ni temi Akanbi
Ki ma ge lọ ni temi Akanbi
Kẹyin kan maa jisoro
Kẹ kan maa jisoro, kan maa jisoro
Kan maa jisoro
Kan maa jisoro Akanbi
Owo n bẹ lapo mi o
Owo n bẹ lapo mi o
Owo n bẹ lapo mi o (Owo n bẹ lapo mi o)
Ẹ kan maa jisoro, kan maa jisoro wa
Kan maa jisoro wa, kan maa jisoro Akanbi
Owo n bẹ lapo mi o
Ọmọge ma foju di mi
To ba foju di mi
O dẹ ti mọ tipẹtipẹ
Wa jọgẹdẹ, wa momi le, wa jẹgba ni tibi
Ki ma fagbo lọ ni temi Akanbi
Ki ma ge lo ni temi Akanbi
Kẹyin kan maa jisoro
Ẹ kan maa jisoro, kan maa jisoro wa
Kan maa jisoro wa, kan maa jisoro Akanbi
Ki ma ge lọ ni temi Akanbi
Kẹyin kan maa ji soro (Owo n bẹ lapo mi o)
Kẹ kan maa jisoro, kan maa jisoro, kan maa jisoro
Kan maa jisoro wa, kan maa jisoro wa, kan maa jisoro wa
Owo n bẹ lapo mi o (Owo n bẹ lapo mi o)
Owo n bẹ lapo mi o
Owo n bẹ lapo mi o
Ẹ kan maa jisoro, kan maa jisoro wa
Kan ma jisoro wa, kan ma jisoro Akabi
Owo n bẹ lapo mi o