Shoday Casablanca Lyrics (feat. Ayo Maff)
Ṣe l’ọn pe mi n zaddy
Mo ni “baby what’s popping?”
Girl I’m chasing money
Ọrọ owo yẹn ṣa lo ba mi
If I no press you money that one no mean say I stingy
As ọmọ ọgbọn mo calcu k’owo ma lọ tan lọwọ mi
Casablanca mo wọ sọrun, mhen I’m looking fresh and classy
Amiri ṣa mo wọ soju, k’aṣiri ma lọ tu
Mo ni Balenciaga mo wọ sẹsẹ, original no be Fugazzi
One million dollar no do me
Ọmọ aye hustle lọ
But mo ni Casablanca mo wọ sọrun, mhen I’m looking fresh and classy
Amiri ṣa mo wọ soju, k’aṣiri ma lọ tu
Mo ni Balenciaga mo wọ sẹsẹ, original no be Fugazzi
One million dollar no do me
Ọmọ aye hustle lọ, hustle lọ
Vanilla Bottega, Vanilla Bottega
With some Lil Kesh
O le jẹ dollar
O le jẹ naira, awa maa nawo o
Ibi re la ma sọ gba si
K’ọmọ owo to gba CC
Nothing wey I never see
A fowo mọti i ku s’ode
So, mo fi Azul to’le
Oniyangi kuro lọna mi
Ṣo mọ nnkan to wa lọkan mi
Ah ah, steeze no go kill me
Valentino lori mi
Fendi lẹsẹ rẹ
O le ku nitori mi
I blow hiroshima nagasaki
Ba mi ṣẹ dollar Rasaki
Balenciaga lọrun mi
When I dey hustle ṣo ri mi?
Casablanca mo wọ sọrun, mhen I’m looking fresh and classy
Amiri ṣa mo wọ soju, k’aṣiri ma lọ tu
Mo ni Balenciaga mo wọ sẹsẹ, original no be Fugazzi
One million dollar no do me
Ọmọ aye hustle lọ
But mo ni Casablanca mo wọ sọrun, mhen I’m looking fresh and classy
Amiri ṣa mo wọ soju, k’aṣiri ma lọ tu
Mo ni Balenciaga mo wọ sẹsẹ, original no be Fugazzi
One million dollar no do me
Ọmọ aye hustle lọ, hustle lọ
K’aṣiri ma lọ tu
Original no be Fugazzi
Ọmọ aye hustle lọ, hustle lọ