Sola Allyson Má Mi’kan I Lyrics, Sola Allyson Má Mi’kan 1 Lyrics
Om’ова o
À rán mi sí o l’eekan si
Èyí l’ohun tí mo gbó
Nígbà ïpôruru okän tèmi
Mo dè mo pé kii se fún èmi nikan
Fún irú u mi
Fún àwa omo, omo imólè
Láti mo n’írin ajò yí o
Pé k’áa má gbàgbé o
Ohun tí mo gbó nígbà iporuru okàn mi
Èyí ni pé k’áa má gbägbé o
Ó ñko sí mi ní kélékélé okän mi
L’ójúbo emí I mi níbití mo ti máa ngbo
Ó níkín má gbägbé o
Irin àjò máa nrí béè n’ígbà mii
B’áyé ti rí niyen kò s’óhun t’áa lè se si
Sugbón om’oba má gbagbé o
Iränwó nbò
Irànwo nbo
Iranwo nbo
Trànwó nbo
Irànwó ñbò omo
Om’oba má gbägbé o
Mo gbó ohün kan nígbä ipöruru okän
Igbätí mo ro gbogbo irin yen o
Mo gbó ohün kan nígbà ipöruru okän
Igbatí mo ro gbogbo iya yen o
Ón wisí mi ní kélékélé okän
Pé kín má gbägbé irapadà mi
Ó nkó sí mi ní kélékélé okän
(l’órísun emí I mi)
Pé kín má gbägbé iräpadà mi
Ó ñ wípé
Om’ова má mikän
Om’oba má s’ojo
Om’oba má gbagbé o
Omo imóle má mikän
Ó mãa ñ rí béè n’ígbà mi
Wãa m’ónà re pon ni
Waá gb’ójú s’óke oò ní gb’ókän s’óki
Gb’ójú s’óke má gb’ókän s’ókè
Isé t’áa rán mi sí o nîyen
Èyí l’ohun tí mo gbó nígbà a tèmi
Mo dè mò pé kií se fún emi nikan
Fún irú ü mi bí iwo
Om’oba má mikän
Om’oba má s’ojo
Om’oba má gbâgbé o
Babá re ló l’ôrò
Bàbá re l’ó l’oore gbogbo
Babá re l’ó ni ògo
Bàbá ol’órò
Bäbá ol’óore
Babá ológo èmi omo ológo
Emi omo ológo babá ológo
Émi omo ológo
Emi l’omo bäbá ol’óore
Èmi l’omo babá ológo
A tira o padà
A tise ó l’óôsó
A ti mú o wolé imólè s’íbi aäyè re
O ti foso s’ayó
A ti so ó d’omo
Om’oba má gbägbé o
A ti rà ò padà
A tise ó loosó
A ti mú o wolé imólè s’íbi aâyè re
O ti foso s’ayó
A tiso ó d’omo
Om’oba má gbagbé o
So that’s our song
Àwa om’oba
Àwa táñ rîrin imóle
Ó mãa ñ ríbéè nígbà mo
Okän mãà ñ s’aáré nígbà mñ
Sügbón aá m’ónà wa pôn ni
Nínú imóle
In the values of god
Om’oba má mikàn
Om’oba má s’ojo
Èrú lè b’omo baba sügbón ibi o lê selè s’ómo baba nítorí
Bàbá wà l’éhin omo baba
Om’ова má mikän
Om’oba má s’ojo
Om’oba má gbägbé o
Eeyan mãa nfé gbagbé nígbämín nígbà ipöruru okän
Ibeere maa npo nigba mii
Sugbon m’ona re pon ninu imole
Sisé imóle, rïrin imole,
R’èro imólè, gb’áyé imóle
Imóle á tàn, á mãa tàn si láti orísun
Láti àgbälá imólè ki kú
Imóle o ní kú fómo imóle
Babá ológo á wà fún omo ológo omo ológo á s’ògo
B’ó ti wù kó rí omo ológo, omo ológo á s’∞go
Nígbà t’ó jé pé bàbá mi l’ó ni ôgo
Baba mi l’ó l’ôrò
Baba mi l’ó l’oore gbogbo
Baba mi l’ó niôgo
Mo ti foso s’ayo
A ti so mí d’omo
A ti mú mi wolé imólè níbi ayee mi
A ti rà mí padà mo ti di omo
I am a child mi ò ní gbägbé o
Om’oba má gbägbé o
I am a child mo d’omo
Mo gbó o mo gbó
I am a child omo l’emi
Mo gbó o mo ti gbó
I am a child of the almighty
Mo gbó o, mo gbó
Èmí mímo so béè fún mi nígba irapadà mi
Mo gbó o, mo ti gbó
Okän mi gbo má gbägbé ilérí I yen
Whatever may come mo gbó
A ti rà mí padà mo ti d’omo
Mo gbó o, mo ti gbó
Baba mi l’ó ni orò
Baba mi l’ó l’oore gbogbo
Baba mi l’óniôgo
Om’oba má mikän
Om’ова má mikàn
Om’oba má s’ojo
Om’oba má gbägbé o
Irin ajò maà n rí béè nígbà mii
Àwa o tiè mo’hun a bá ñle
Má s’ ojo o
Niwon igbà t’óo bá ti t’öna imóle
Má mikän,
Wá wolé sínú ilé imólè, come, come
Wá wolé o omo, sílè imóle, níbi imóle, wá wolé síbi aäye re
Bàbá re l’ó l’ôrò
Bàbá re l’ó l’oore gbogbo
Babá re l’ó ni ôgo
Àb’ód mò ni
Àb’óò mo ni
Àb’óò ti gbägbé
Baba à re ni
Baba imólè ol’órísun imóle
Ol’órísun ohun gbogbo o
Bàbá re l’ó l’ôrò
Bàbá re l’ó l’oore gbogbo
Baba re l’ó ni ogo
A tira ò padà
Atise ó lósó
A timú o wole imolè síbi aâyè re o