Lyrics

Sola Allyson – Má Mi’kan II Lyrics

Sola Allyson Má Mi’kan II Lyrics, Sola Allyson Má Mi’kan 2 Lyrics

Nobody knows what tomorrow may bring
Olúwa nïkan ló’ m’ôla
Nobody knows what tomorrow may bring
Olúwa nikan ló’ mö’ la
Ïgbágbó tí mo ní ni whatever ti brings
Olúwa à mi s’olódodo
Ïgbágbó tí mo ní ni whatever ti brings
Olúwa à mi s’olódodo

Baba mi ló’ lo’ro
Baba mi s’olóòdodo
Baba mil’ó níògo

Are you afraid sometimes?
Bäbá er ló’ lo’rò, ma gbägbé
Babá re ló’ lo’ ore gbogbo
Babá re ló’ ní ôgo

So you’re thinking “How can I move ahead”
Bäbá re ló’ l’oore gbogbo
Di baba à re mú ife e bäbá à re

Bâbá à re ló’ni orò má gbâgbé
In the questions of your heart
Di olúwa mú, ro mó opó igbagbó ò re
Babá re ló’ lo’rò, súnmó o, súnmó o omo
Bàbá à re l’ó ni ògo

Om’oba má mi’kän
Om’oba má s’ojo
Om’oba má gbägbé o

Bäba re ló’ lorò
Bäbá re ló’ lo’ore gbogbo
Bäbá re ló’ níôgo

A ti rà ò padà
A ti se óló’só
A ti mú o wolé imólè níbi äayè re
A ti fó’só s’ayó
A ti so ó do’mo o
Om’oba má gbägbé

You know, ican relate, with anything that.
I mean, we may not be going through the same things but
By principle, we carry pain
Because of the things that had happened to us
By now, if you know me, you know that I can relate
But ni the time of my own questions, I heard
Om’oba, om’oba, omo’ ba ooo om’oba, ma, ma mik’än
Om’oba má mikän
Om’oba má s’ojo
Om’oba má gbägbé

Its’ because mo n mïk’än, its’ because I was mi’kän-ing
Tórí mò n mik’än ni mo se gbó má mik’än nãó
It was because I was fretting was why I heard not to fret
Ti was because I was fearful was why I heard not be fearful
It was because I was almost being cowardly was why I heard not to be cowardly

Má mikän
Má s’ojo
Má gbägbé

Má mikän fret not
Má s’ojo not be acoward you know
Om’oba má gbägbé o
I can relate to what you’re going through
Bi ò tie selè sí mi mo ní tèmi
Omo bá má gbâgbé o

Ibi ogo tí mò n lo ibè ni mo d o’jú ko
That’s where my focus is
Síbè mi ò ní gbägbé o
Ohun tó n selè ló’nã ôgo
Síbè mãá di bäbá àmi mú
Om’oba má gbâgbé o

Is ti in your studies?
Is ti from home?
Is ti in your marriage?
Is ti in your work?
Is it because you’re looking for a child?
Is it because of your health?
Everybody, al of us we have something
But your father has sent me to you
When he took me to the lowest of lows
To tell you that you should not forget om’oba

Om’oba má mi’kän
Sé ara à re bí om’oba
Omo’ ba ni ó, hù w’à bí omo’ ba, hen, béèni
Hù w’à bí om’oba, se bí om’oba, rin bí omo’ba
Ro bí omo’ ba o, omo’ ba má gbagbé o

Om’oba ma mi’kän
Om’oba má s’ojo
Om’oba má gbägbé o

Se bí om’oba
Gbé ayé ère bí om’oba o
Ro èrò bí om’oba
Hü’wà bí om’oba

Bäbá re ló’ lo’rò
Babá re ló’ l’oore gbogbo
Babá re ló’ ní ògo

A ti rà ópadà
A ti se ólosó
A ti mú o wolé imólè níbi ãayè re
O ti fó’só s’a y o
A ti so ó do’mo
Om’oba má gbâgbé o

Om’oba má mik’ än
Om’oba ma s’ojo
Om’oba ma gbägbé

Èdá t’o m’ôla kò sí
Èdá to’ m’ôla kò sí
Èdá t’o m’ôla kò sí
Asán lä’ yé nse

Èdá to’ m’ôla kò sí

Do not give up om’oba
Èdá to’ m’ôla kò sí o the story is still being written
Èdá to’ m’ôla kò sí
Asán l’ävénse

Ïmò asán ni t’ayé
Îmò asán ni t’ayé
Îmò asán ni t’ayé
Asán l’ayé nse

Îmò asán whatever they have told you si a lie
Îmò asán ni they said you would not amount to anything it’s a lie
Imò asán ni ta’yé
Asán la’ yé nse

Maybe it’s even your mistake
So because of that they’re defining you by your mistake
You too stop making the mistake and be new! God loves
You still!
Asán l’ayéñse

Sãà gbékèlé olúwa
Sãà gbékèlé olúwa
Sãà gbékèlé olúwa
Sá gb’ékè re le

Ení bá gbékèlé olúwa ó gbódò sè’fé olúwa
Enit’ó bá sè’fé olúwa ló’ mãa j’èrè ilérí olúwa
Sá gbé’ kè er él olúwa
Sá gbé’ kè re le